GOSPEL MUSICLYRICSVIDEOSWESTERN SONGS

Sola Allyson – Iwo Nikan (Mp3 Download & Lyrics)

CLICK HERE TO DOWNLOAD FAST!!!
Sola Allyson – Iwo Nikan
Sola Allyson – Iwo Nikan

This is a stunning song from the Nigerian soul, folk and gospel singer and songwriter who has taken the spotlight with his hit album Eji Owuro. Sola Allyson-Obaniyi, known colloquially as Shola Allyson, named the song “Iwo Nikan”.

Iwo Nikan is a nice Gospel song in which we recommend you to listen to And should be added to your playlist.

Download Iwo Nikan Mp3 By Sola Allyson

DOWNLOAD MP3

Iwo Nikan lyrics By Sola Allyson

Iwo nikan ma loga ju

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma loga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma loga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma loga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma loga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Ayin o oo

Ayin o oo

Iwo nika ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye o

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nika ma lo ga ju

Iwo nikan niyin ye o

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Oba airi Aripa re nipa imisi

to fi saye fun anfani wa ni gbogbo won

Iwo to fe wa oloore

Ki laba fi yin o aoti e mon

Aomaa wa ninu ifeere

A o ma sin niGbagbogo fun ola re Olola o

Iwo nika ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin

Iwo nika ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin

A o ri o arise re fun gbogbo eda too da saye

Ise re po Oju oye lo asin o oloore

Titi aye lao ma sin

Titi aye laoma yin o

Onike onige fun gbogbo wa

Afogo fun o Ologo

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin

Iwonikan (3x)

Ab’ola fun o ayin o

Iwonikan (3x)

Ab’ola fun o ayin o

Iwonikan (3x)

Ab’ola fun o ayin o

Iwonikan (3x)

Ab’ola fun o ayin o

Kabiyesi re aileyipada

Onise nla tio see tu

Talo lo si Ko mon nkankan

Ibukun funye Iranwo wa

Iwo to wa loo ma wa

Ole yipada titi lae

Ab’ola fun o Oba wa

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Ayin o oh (2x)

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye o

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye o

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

Iwo nikan ma lo ga ju

Iwo nikan logo ye

Iwo nikan ma loga ju

Laye lorun ayin o

The End!

Leave a Reply