
Here comes Sola Allyson a Nigerian gospel minister she releases new track titled Imisi (and it came with an official Lyrics) for you to read as you listen and enjoy the song.
Imisi is one of the Trending gospel song out there you would love to listen to.
Download Imisi Mp3 By Sola Allyson
Imisi lyrics By Sola Allyson
Imole ko tan s’okunkun
Idari ko wa lona
Epo ko wa l’atupa
Lai ni tan
Emi mimo, mo beere
(Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n’irinajo
Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan
Imole ko tan s’okunkun
(Imole ko tan roro lati agbala, imole)
Idari ko wa lona
(Epo ko wa), wpo ko wa l’atupa
(Ti o ni tan, ti o ni tan), lai ni tan
Emi mimo, mo beere
(Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n’irinajo
Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan
Ti o ni tan, ti o ni tan
Ti o ni tan, ti o ni tan
Imole ko tan s’okunkun
(Itansan imole to mole roro)
Idari ko wa lona
Epo ko wa l’atupa lai ni tan
Emi mimo, mo beere
(Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n’irinajo
Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan
Oba imisi, Oba imole
Oba Aanu, Oba Ogo
Orisun imisi, Isewa imole
Je ki imisi ba le mi
Lati odo re
Oba imisi, Oba imole
Oba Aanu, Oba Ogo
(Aanu to mu mi de bi koni ju mi le)
Orisun imisi, Isewa imole
Je ki imisi ba le mi
Ti o ni tan
Ti o ni tan, ti o ni tan (koni tan lati agbala)
Ti o ni tan, ti o ni tan
Imole ko tan s’okunkun
(Idari ko wa), odari ko wa lona
Epo ko wa l’atupa (atupa imo mi o ni ku lai-lai)
Lai ni tan
Emi mimo, mo beere
Waa—, wa gbe mi wo n’irinajo
Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan
Oba imisi, Oba imole
Oba Aanu, Oba Ogo
Orisun imisi, Isewa imole
Je ki imisi ba le mi
Lati odo re
Oba imisi, Oba imole (imisi lati agbala imisi)
Oba Aanu, Oba Ogo
Orisun imisi, Isewa imole
Je ki imisi ba le mi
Lati odo re
Oba imole
(Itasan Imole to mole roro)
Oba Aanu, Oba Ogo (aanu to mu mi debi o ni ju mi le)
Orisun imisi (ibe ni mo gboju soke si), Isewa imole
Je ki imisi ba le mi
Ti o ni tan
Ti o ni tan, ti o ni tan
(Ko ni tan lailai, ati agbala imisi n’imisi ti n wa)
Ti o ni tan, ti o ni tan
Imole ko tan s’okunkun
(Idari ko wa lona mi)
Idari ko wa lona
(Epo ko wa l’atupa o)
Epo ko wa l’atupa lai ni tan
Emi mimo, mo beere
Waa—, wa gbe mi wo n’irinajo
Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Okun o gberi, osa o gberi o, ise Baba oni imisi ni won
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Itansan imole yen ko ma tan fun mi ni irinajo mi
Lati odo Oba oni imisi, lati agbala imisi
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Imisi ko wa fun mi, ta fi irisi omo Baba imole han nigbagbogbo
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Imisi ta ko mi ni isesi imole ni gbogbo irinajo mi, lona mi
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Imisi ta fi irisi omo baba oni imisi han, ko wa fun mi nigbagbogbo
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan