
Asise O Si By Sola Allyson, is made available for you to get and digest. sing the song fluently like the real artist and do your cover or anything your will like to do the with the impressive song.
Asise O Si is an Amazing song that everyone would love to listen to.
Download Asise O Si Mp3 By Sola Allyson
Asise O Si lyrics By Sola Allyson
Ibere Po lokan mi
Sugbon Momo poluwa dara
Irin ti mo ri ojin gan
Sibe Sibe mo mo poluwa dara
Awon Ibere Yi wa nko
Idahun yen Nibo nati wa
Olutoni farahan mi o
Lori Ibere to wa lokan mi
Ibere Po lokan mi
Sugbon Momo poluwa dara
Irin ti mo ri ojin gan
Sibe sibe mo mo poluwa dara
Awon Ibere Yi wa nko
Idahun yen Nibo nati wa
Olutoni farahan mi o
Lori Ibere to wa lokan mi
Sugbon mo mo asise osi loro re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
Igbamiran gbogbo re ati sunni
Sibe ninu e momo poluwa dara
Ibi ti mo nlo osi jin gan ni
Itoni ni mobere ajo ko san mi o
Awon Ibere Yi wa nko
Idahun yen Nibo nati wa
Olutoni farahan mi o
Lori Ibere to wa lokan mi
Sugbon mo mo asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
Itura a de o Iranwo a wa
Moni ireti Asise osi o
Itura a de o Iranwo a wa
Moni ireti Asise osi o
Itura a de o Iranwo a wa
Moni ireti Asise osi o
Itura a de o Iranwo a wa
Moni ireti Asise osi o
Sibe sibe mo mon asise osi
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re