GOSPEL MUSICNIGERIAN SONGS

Oladele Tumininu – Mo faye atife mi fun (Mp3 Download, Lyrics & Video)

Oladele Tumininu - Mo faye atife mi fun
Oladele Tumininu – Mo faye atife mi fun

Fast-rising Nigerian Minister Oladele Tumininu song titled Mo faye atife mi fun

Mo faye atife mi fun is a Yoruba worship song you can put to your playlist.

Download Mo faye atife mi fun Mp3 By Oladele Tumininu

DOWNLOAD MP3

Mo faye atife mi fun video By Oladele Tumininu

Mo faye atife mi fun lyrics By Oladele Tumininu

Mo f’aye at’ife mi fun
Od’aguntan to ku fun mi;
Je ki n le je olotito,
Jesu Olorun mi.

Refrain:
N o wa f’Eni t’O ku fun mi,
Aye mi yo si dun pupo;
N o wa f’Eni to ku fun mi,
Jesu Olorun mi.

Mo gbagbo pe Iwo n gbani
‘Tori ‘Wo ku k’emi le la;
Emi yo si gbekele O,
Jesu Olorun mi.

Iwo t’O ku ni Kalfari,
Lati so mi dominira;
Mo yara mi soto fun O,
Jesu Olorun mi.

Leave a Reply