
Emmanuel Edunjobi popularly known as Emma Oh My God is a Nigerian comedian, singer, actor, event host and content creator.
Oba ni Jesu (Live) is a marvelous song performing live By EmmaOMG & His Brilliant Crew The OhEmGee Band.
Download Oba ni Jesu (Live) Mp3 By EmmaOMG & The OhEmGee Band
Oba ni Jesu (Live) video By EmmaOMG & The OhEmGee Band
Oba ni Jesu (Live) lyrics By EmmaOMG & The OhEmGee Band
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oh! Oh! Oba ni Jesu
Mo ti sonu sinu igbekun ese mi
Si afonifoji iku a ti gbagbe mi
A ti to mi pin pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo jebi gbogbo esun ta kan mo mi
Ide mi ja, mo d’ominira
Lati igba mo ti mo Jesu
A ti san gbese mi nipa Eje Jesu
Jesus, yours is the victory
Hallelujah! Praise the one who sets me free
Hallelujah! Death has lost his grip on me
You have broken every chain
There is salvation in your name
Jesus Christ, my living hope
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oh! Oh! Oba ni Jesu
Mo ti sonu sinu igbekun ese mi
Si afonifoji iku a ti gbagbe mi
A ti to mi pin pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo jebi gbogbo esun ta kan mo mi
Ide mi ja, mo d’ominira
Lati igba mo ti mo Jesu
A ti san gbese mi nipa Eje Jesu
Jesus, yours is the victory
Hallelujah! Praise the one who sets me free
Hallelujah! Death has lost his grip on me
You have broken every chain
There is salvation in your name
Jesus Christ, my living hope