GOSPEL MUSICNIGERIAN SONGS

Mrs Fasoyin – Odun Yi Atura (Mp3 Download & Lyrics)

Mrs Fasoyin - Odun Yi Atura
Mrs Fasoyin – Odun Yi Atura

Download this marvelous melody titled Odun Yi Atura by CAC Good Women Choir, Ibadan. Led by Mrs D. A Fasoyin.

Odun Yi Atura was released under the stable of CAC Good Women Choir.

Download Odun Yi Atura Mp3 By Mrs Fasoyin

DOWNLOAD MP3

Odun Yi Atura lyrics By Mrs Fasoyin

Odun yi atura ko ni leKoko mo mi,
Odun yi atura ko ni leKoko mo mi,
Ohun ti mo da’wo ayori,
Ohun ti mo beere l’oluwa yio se,
Odun yi atura ko ni Koko mo mi
Odun yi atura ko ni Koko mo mi X2
Ohun ti mo da’wo le ayori,
Ohun ti mo beere l’oluwa yio se,
Odun yi atura ko ni Koko mo mi

[Verse 1]
olorun o seun f’Odun to koja X3
Eyi ti beere, ko tu WA lara,
olorun o seun f’Odun to koja,

[Chorus]
Odun yi atura ko ni lekoko mo mi,
Odun yi atura ko ni lekoko mo mi,
Ohun ti mo da’wo le ayori
Ohun ti mo beere l’oluwa yio se
Odun yi atura koni Koko mo mi
(instrumenting)…..

[Verse 2]
Olorun wa jowo s’Odun l’abo..X2
olorun wa jowo s’Odun l’abo..X2
Odun t’abere ko sanwa s’owo
Odun t’abere ko sanwa s’omo
olorun wa jowo s’Odun l’abo

[Chorus]
Odun yi atura koni lekoko mo mi
Odun yi atura koni lekoko mo mi
Ohun ti mo da’wo le ayori,
Ohun ti mo beere l’oluwa yio se
Odun yi atura koni lekoko mo mi
(instrumenting)…

[Verse 3]
L’Odun titun, Baba se rere fun mi,
kin tire GBA, kin mase lo lofo…X2
Odun Ayo kin ri bati se, maje nsofo,
maje ndamu Lori omo,
Odun Ayo, Baba se rere fun mi
[Chorus]
Odun yi atura koni lekoko mo mi
Odun yi atura koni lekoko mo mi
Ohun ti mo da’wo le ayori
Ohun ti mo beere l’oluwa yio se
Odun yi atura koni lekoko mo mi
(instrumenting)…

[Verse 4]
Odun t’abere ko sanwa fun rere
k’ama se mo OSI, ko tu WA lara..X2
Igba aalee, awo aalee, anikun Ohun rere
Kii tan ninu igba osuun, k’ama fi r’amo Lori,
Edumare a gbe WA leke, a dojuti elegant
Odun t’abere a sanwa si rere.

[Chorus]
Odun yi atura koni lekoko mo mi
Odun yi atura koni lekoko mo mi
Ohun ti mo da’wo le ayori
Ohun ti mo beere l’oluwa yio se
Odun yi atura koni lekoko mo mi
reading
Eni ko ini, e ma banuje,
edumare ti Segun Ase daju
onise owo ama rise

Leave a Reply