GOSPEL MUSICNIGERIAN SONGS

Itunu Cole – Ojo Agbara Na Ti Osan Doru (Mp3 Download & Lyrics)

Itunu Cole - Ojo Agbara Na Ti Osan Doru
Itunu Cole – Ojo Agbara Na Ti Osan Doru

Nigerian gospel artiste Itunu Cole releases a new single off his forthcoming album, titled “Ojo Agbara Na Ti Osan Doru”.

This is a song that praises God as the author and finisher, The God that answers to all our heart desires. The God that has the final say on everything. This praise song will have you singing your heart out in joy for God.

Download Ojo Agbara Na Ti Osan Doru Mp3 By Itunu Cole

DOWNLOAD MP3

Ojo Agbara Na Ti Osan Doru video By Itunu Cole

Ojo Agbara Na Ti Osan Doru lyrics By Itunu Cole

… OJO AGBARA NA
… All: Ojo agbara na ti osan doru
T’aso ‘jo mimo kale
Irawo meje loyo ni oke orun
Awon eye iwo nke luli
Awon eye iwo nke luli
Luli ore-ofe
Irawo meje loyo ni oke orun
Awon eye iwo nke luli
… L/v: Osu kesan ojo Kankandinlogbon
Ni odun 1947, ni eyi sele
… All: Ni eyi sele, lagogo meta osan
Gbowo SBJ Oshoffa
Eyi loko ikehin
To sokale latorun
Iye, iye, iye lohun na nke
Ijo Mimo Celestial
… Int: Mo mbe ninu ododo
… All: Ise lohun na ke emura sise
Sise pelu ‘fe mimo
Ere ise re ni iwo yio gba o
Sise pelu’fe mimo
Ejeka mura sise
Sise pelu ife mimo
Ere ise re ni iwo yio gba o
Sise pelu ‘fe mimo
… All: Ero ara ota loje s’Olorun
Idunnu Olorun l’emi
Iye awa to gba jesu l’oluwa
Eje ka sin ninu ife
Eje ka sin ninu ife
Eje ka sowopo
Iye awa to gba jesu l’oluwa
Eje ka sin ninu ife
… All: Ife lohun na ke
Eje kalo ‘fe
Bi iwe mimi tiwi
Korinti kinni, Ori ketala
Ife lohun na nko wa
Bere la tese kinni,
Titi de ipari re
Korinti kinni, ori ketala
Ife lohun na nko wa
… All: Igbagbo ni idaniloju
Ohun ti a nre ti
Ijeri ohun ti a kori
Oniyemeji ki yio ri ohunkohun gba
Jesu Kristi to fun wa
Eni to bani Jesu
Ohun lohun bori aye
Oniyemeji ki yio ri ohun kohun gba
Jesu Kristi to fun wa
… All: Eje ka toro agbara isin dopin
Ibere ko loni se
Lawa le r’ode iye ti ati pese
Sile fun ijo mimo
Ibere ko lonise
Bi kode aisedopin
Eje ka sise ka le gba de ogo
Ta pese fun ijo Mimo
… L/v: Ijo mimo, latode Orun
Baba wa Orun , lofi ranse o
B’aye fe, baraye ko,
Yio bori dandan
B’ota fe bi satani ko
Ife Oluwa ni lati se
… All: Bi gbogbo aye, dite mowa
Won gbodo teri ba fun Oluwa
Eyin omo Ijo mimo
Edide keyin Oluwa
Halleluyah ni orin wa
Halleluyah wa ninu ise wa
Bi aye fe, bi aye ko 2x
Won ateriba fun Oluwa
… L/v: Awa n’jo mimo, Aladura
… All: Ijo mimo dara
Jesu baba wa f’ohun
Rere sile
Inu wa si dun, Halleluyah
… All: Awa nyo ninu Jesu
Jesu mbe lehin wa
Ohun gbogbo ti a
Mbere lowo re
Osi ti fi fun wa, Haleuyah
… All: Awa nijo mimo
Ijo mimo mbe
Awon angeli yo
Pelu wa

Ara was i ti ya, Halleluyah.
… All: Apalase lagbala orun
Pe’ ki’jo yi ma bisi
Apalase lagbala orun
‘pe kosi maa re si
Titi gbogbo iponju aye 2x
Yio fi tan laye
Titi jesu olugbala
Yio fi pada wa
… Interlude:
… All: Omo njo, Omo nyo
Nigbati, baba wa nyo
Pelu orin ayo
Halleluyah la o ma ko
Nigbati maleka nyo 2x
Pelu orin ayo
Mimo mimo lao mako
Nigbati oba ogo
Sewa logo
… Intro: iwo kuku n’mole wa
Emimimo e seo
… All: Emimimo Ade o
Emi awon woli
iwo kuku n’mole wa
Ninu ijo mimo
… All: Emimimo Ade o
Emi awon woli
iwo kuku n’segun
Ninu ijo mimo
… All: Emimimo Ade o
Emi awon woli
iwo kuku lagbara ra wa
Ninu ijo mimo
… L/v: Baye bawa gbogun de
… All: awa la o bori won
… All: awa la o leke won
Fona abayo han wa o, baba awa.
… L/v: Iwo kuku lagbara wa
Emimimo a de o
… All: Emimimo ade o
Emi awon woli etc. 3x
… L/v: Wo o le All: Adaba mimo
L/v: Wo o le All: Adaba Ogo
L/v: Adaba All: Adaba towa lehin ogba
Adaba ologo
Adaba mimo o, Wo o le
… L/v: Iwo kuku nimole wa
Emimimo atide
… All: Emimimo Ade
Emi awon woli .etc/ 3x
… L/v: Iwo kuku latona we ninu ijo mimo
Iwo ko nsowa lo ndabobo wa loojo jumo
Iwo kuku lafi nriran ninu ijo Celestial Church
Emimimo Sokale wa, bawa ton ijo mimo se to
Holy spirit sokale wa, was a ko so ijo mimo
… L/v: Gbogbo Agbara /2x Jesu lowo Re lowa
Kosi lowo oso o, koma si lowo aje o rara
… All: Gbogbo agbara, gbogbo agbara
Jesu lowo Re lowa
… L/v: Iwo kuku nimole wa ninu ijo mimo o
… All: Emimo ade o, Emi awon woli. Etc.

Leave a Reply