GOSPEL MUSICNIGERIAN SONGS

EmmaOMG – Oba Ni Jesu (Mp3 Download & Lyrics)

EmmaOMG - Oba Ni Jesu
EmmaOMG – Oba Ni Jesu

Nigerian christian music minister Emma OMG is here again with a brand new sound of adoration and worship titled Oba Ni Jesu (Moti Sonu Sinu Igbekun Ese Mi).

Oba Ni Jesu is a wonderful Yoruba song that will uplift you.

Download Oba Ni Jesu Mp3 By EmmaOMG

DOWNLOAD MP3

Oba Ni Jesu video By EmmaOMG

Oba Ni Jesu lyrics By EmmaOMG

Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oh! Oh! Oba ni Jesu

Mo ti sonu sinu igbekun ese mi
Si afonifoji iku a ti gbagbe mi
A ti to mi pin pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo jebi gbogbo esun ta kan mo mi

Ide mi ja, mo d’ominira
Lati igba mo ti mo Jesu
A ti san gbese mi nipa Eje Jesu

Jesus, yours is the victory
Hallelujah! Praise the one who sets me free
Hallelujah! Death has lost his grip on me
You have broken every chain
There is salvation in your name
Jesus Christ, my living hope

Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oh! Oh! Oba ni Jesu

Mo ti sonu sinu igbekun ese mi
Si afonifoji iku a ti gbagbe mi
A ti to mi pin pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo jebi gbogbo esun ta kan mo mi

Ide mi ja, mo d’ominira
Lati igba mo ti mo Jesu
A ti san gbese mi nipa Eje Jesu

Jesus, yours is the victory
Hallelujah! Praise the one who sets me free
Hallelujah! Death has lost his grip on me
You have broken every chain
There is salvation in your name
Jesus Christ, my living hope

Leave a Reply