DOWNLOAD MP3: Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

0


Tope Alabi Loro Lero Ati Nise
Tope Alabi Loro Lero Ati Nise Mp3 Download

TOPE ALABI comes through with yet another new song titled “LORO LERO ATI NISE” and is right here for your fast download.

Listen & Download Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise below:-

DOWNLOAD AUDIO

Loro Lero Ati Nise Lyrics by Tope Alabi Hymnal

Verse 1
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise
Chrous:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Verse 2
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise
Verse 3
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

SHARE

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here