
Off the album“Hymnal Vol 1 Album” by Tope Alabi comes this soul filled tune titled “Eyin Oluwa Halleluyah”.
Nigerian Gospel performer “Tope Alabi” dished “Eyin Oluwa Halleluyah” off the just delivered Album. enjoy and share!
Listen & Download Tope Alabi – Eyin Oluwa Halleluyah below:-
Eyin Oluwa Halleluyah Lyrics by Tope Alabi
Verse 1:
Eje ka f’ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai
Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah
Verse 2:
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun
Verse 3:
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo
Verse 4:
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo